Orílẹ̀-èdè Russia sọ ni ọjọ́ ajé pé orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà sì ń se atìlẹ́yìn fún orílẹ̀-èdè Ukraine.
” Wọ́n fẹ́ ṣíwọ́ ìrànwọ́ wọn,” igbákejì Mínísítà ilẹ̀ òkèèrè fún ilẹ̀ Russia, Sergei Ryabkov sọ èyí bí ìròyìn láti State news agency TASS se sọ.
Atìlẹ́yìn ilẹ̀ Washington fún àwọn tirẹ̀ ni
Kyiv kò yípadà,”Ryabkov sọ èyí.
Ilẹ̀ Amẹ́ríkà ti lo owó tó dín díẹ̀ ní àádọ̀ta bílíọ̀nù Dọ́là fún ìrànwọ́ ètò àbò sí ilẹ̀ Ukraine láti ìgbà tí ìkọ̀lù Russia sí Ukraine ti bẹ̀rẹ̀.ni oṣù Kejì ọdún 2022.
Bíi ìpèsè àdó olóró, ohun ìjà Ogun, èròjà ogun àti ọgbọ́n àtinúdá.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply