Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà Ní Látí Ṣé Ayẹyẹ Ọdún Òmínírá Ní Ìwọ́nbá

0 326

Àkọwé Ìjọba àpapọ̀ SGF, Ọ̀gbẹ́ni George Akume sọ pé ayẹyẹ́ Ọjọ́ Omínírá kẹtàlélọ́gọ́ta 63rd tí Nàìjíríà tó nbọ̀ ní ọjọ́ kíní Oṣú Kẹ́wàá yòó jẹ́ ní ìwọ́nbá.


Sẹnetọ Akume tó tún jẹ́ alagá ìgbímọ̀ àwọn minisita lori ayẹyẹ ọjọ ominira lo sọ eyi di mimọ ni ọjọ Aje lasiko ipade awọn oniroyin agbaye, to waye nilu Abuja.

Ó sàlàyé pé ní ìbámu pẹ̀lú àwọn òtítọ́ ètò ọrọ̀ ajé tó wà lórílẹ̀-èdè náà, Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu fi ìfọwọ́sí rẹ̀ fún ayẹyẹ ọdún kẹtàlélọ́gọ́ta yìí láti tẹnumọ́ ọn pé koko ayẹyẹ náà ni “Nigeria @ 63, Renewed Hope for Unity & Prosperity. ”

SGF tun ṣe agbejade ilana eto lati samisi Ọjọ Ominira yii pẹlu;

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button