Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó, Ìwọ̀ òòrun guusù orílẹ̀-èdè Náìjíríà, ní ọjọ́ Áìkú, fún àwọn olúgbé àti ontájà òpópónà ojú-ìrìn Èkó sí Badagry wọ́nyí ní ọjọ́ méje láti kúró pátápátá tábi páda sẹ́yìn.
Òpópónà Lagos-Badagry naa ni ojuna ọkọ oju-irin Blue Line wa lati Orile si Iyana Iba.
Komisona fun Ayika ati Awọn orisun Omi, Ọgbẹni Tokunbo Wahab, ṣe agbejade ikilọ naa nigbati O ṣe abẹwo opopona ọkọ oju-irin naa.
O tẹnumọ pe o ṣe dandan lati rii daju pe awọn eniyan kuro loju popo naa, eyi to jẹ irufin ọja tita ati ibugbe.
Leave a Reply