Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà FCT fi ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ta àwọn olóyè ìpele kẹta lọ́rẹ

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 397

Mínísítà Nàìjíríà ti olú ìlú, FCT, Nyesom Wike ti fa ọkọ̀ ayọ́kélẹ́ le àwọn Olóyè ìpele kẹta mẹ́wàá lọ́wọ́ ní olú ìlú tí ó sì tún pinnu láti ṣe àtúnṣe lórí ìgbé ayé ìrọ̀rùn fún àwọn olóyè náà.

Awọn oloye ipele kẹta naa ni  Gomani, Yaba, Bwari, Pai, Garki, Jiwa, Wako, Rubochi, Gwargwarda, ati Zuba, ti gbogbo wọn si wa ni ilu Abuja, olu ilu Naijiria.

Nigba ti o n fun awọn oloye naa kọkọrọ ọkọ ayọkẹlẹ Nissan Semi SUV, minisita ṣalaye pe iṣe yii wa lara akitiyan ijọba lati mu lilọ bibọ awọn oloye naa o rọrun.

Wike sọ pe ni ibamu pẹlu Atunṣe ipinnu aarẹ Tinubu, gbogbo awọn to nii ṣe ni ipa lati ko, ti awọn oloye naa si jẹ ọkan lara wọn, paapaa julọ ni abala aabo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button