Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Iṣé Alàádáni Ṣẹ Ìrànlọ́wọ́ Àwọn Ohùn Ìtura Fún Àwọn Tí O ṣe Àgbákò Àwọn Oníṣe Láabi.

0 168

Ilé Iṣé Alàádáni ti amò sí Victims Support Fund (VSF) ti ṣe ìrànlọ́wọ́ àwọn ohun ìtura tó tó ẹgbẹ̀rún mẹ́ta fún àwọn tí ó’ se ìjàmbá àwọn láabi  ni ìpínlẹ̀ Kaduna.

Àwọn ìbílẹ̀ tó jẹ ànfààní náà ni Chikun, Giwa ati Zangon Kataf, àwọn ènìyàn tó tó ẹgbẹ̀rún kàn láti àwọn ìbílẹ̀ kankan lo je ànfààní náà.

Àwọn ohun tí wọn Pin náà ni, àpò ìrẹsì, Ẹwà, òróró, iyọ, Suger àti Maggi.

Lára àwọn tó jẹ ànfààní náà ní, Ìyáàfin Eunice Chukwu dúpẹ́ gidigidi lọ́wọ́ ilé iṣé alàádáni náà, o ni àwọn ohun ìtura náà je ànfààní nlá gidigidi fún àwọn.

O kí Olùdásílẹ̀ ilé iṣé náà fún àtìlẹ́yìn rẹ àti ìrànlọ́wọ́ fun àwọn mẹ̀kúnù

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button