Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Tó Ń Gbógun Ti Ìwà Ìbàjẹ́ Ní Kenya Gbá Gómìnà Tẹ́lẹ̀rí Mú

0 204

 

Ọlọ́pàá orílẹ̀-èdè Kenya ti gbà Gómìnà tẹ́lẹ̀ rí àti ìyàwó rẹ̀ mú lórí àwọn ẹ̀sùn ti kò dára tí wọ́n fi kan wọn, oníròyìn ìbílẹ̀ sọ èyí.

Ìdí pàtó tí wọ́n fi gbá wọn mú tàbí tí wọn ń fi wáàdí wọn kò ti di sísọ ní àkókò yi.

Ọ̀gbẹ́ni Oparanya lọ ọdún méjì bí Gómìnà wọn ní Kakamega County ni ìwọ̀ Oòrùn Kenya láàrin ọdún 2013 sí 2022.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button