Take a fresh look at your lifestyle.

Ọjọ Omoniyan: UNFPA Ṣé Ìlérí Àtìlẹ́yìn Fún Àwọn Obìnrin Àtí Ọmọbìnrin Ìpínlẹ̀ Zamfara

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 228

Àjọ United Nations Population Fund (UNFPA) tí tún ṣé ìdánilójú àtìlẹ́yìn rẹ̀ fún àwọn Obìnrin àti àwọn ọmọbìnrin ní àwọn àgbègbè ibùdó àwọn tí wọ́n f’ipa ṣí nípò ní Zamfara lórí ìbálòpọ̀ àtí ìlera ìbìmọ́.

Olórí UNFPA tí Ìpínlẹ̀ Kaduna, Ìyááfín Loide Amkongo sọ èyí níbí ìwọdé kàn látí ṣé ìrántí Ọjọ́ Ọmọnìyàn Àgbáyé 2023 ní Gusau, Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Zamfara.

Ìwọdé náà ní a ṣètò nípasẹ̀ Ilé-iṣẹ́ Ìtọ́jú Pajawiri tí Ìpínlẹ̀ (SEMA) ní ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú Àjọ UNFPA.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button