Ilé iṣé ìjọba fún ọ̀rọ̀ ìlera sọ wí pé àwọn yóò pèsè gbogbo ohun elo ti àwọn òṣìṣẹ́ nílò lórí ọ̀rọ̀ àìsàn kògbọ́ògùn ni Orílẹ̀-èdè nàìjíríà.
Mínísítà fún ètò ìlera, Ìyáàfin Kachllon Daju ti ọ̀gbẹ́ni Gbenga Ijaodola sójú fún ní ilé iṣé ìjọba yóò sa gbogbo ipá re látí ri wí pé ó bó si.
Nínú ọ̀rọ̀ rẹ ó ní ètò ìlera lágbaye, ni ètò ati ìlànà tí wọn ń Ṣíṣẹ́ le lori, èyí tí sí mú wọn pèsè dátà ti yóò mú kí iṣé náà yà ní kiakia
Dọ́kítà Oyeledun to jẹ Alakoso agba fún ọfisi CHIP sọ wí pé ètò náà wàye àti ànfààní fún àwọn tó ní àìsàn kògbọ́ògùn àti láti ṣe ìwúlò dátà lilọ fún wọn
Ó ní CHIP n bá ìjọba ṣíṣẹ́ àti àwọn tọ́rọ̀ kan láti lè rí wí pé àṣeyọrí ba àwọn tó ní àrùn kògbọ́ògùn. Ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Leave a Reply