Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Osun Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Agbègbè Fún Iṣé Abẹ Áti Ìtọ́jú Fún Àwọn Ènìyàn.

0 282

Gómìnà ìpínlẹ̀ Osun, Ademola Adeleke tí ṣe ìfilọ́lẹ̀ agbègbè tó bójú mu fún iṣé abẹ àti ìtọjú fún ìlera àwon ará ìlú ní ìpínlẹ̀ ọ̀sun láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ìlera.

Gómìnà Adeleke to sọ èyí di mímọ̀ sọ wí pé ètò náà wà fún àwọn tí o nilo ìtọ́jú ni pa ìlera.

Ó ní ìjọba òun ti pàṣẹ gbogbo ohun ti wọn yóò nílò fún iṣé náà , ó ni dìgi oju náà ko gbẹyin fún àwọn arúgbó náà.

Kọmísọ́nà fún ètò ilera Kola Akintola ni Gómìnà gbé ọ̀rọ̀ ìlera ṣọkan gidigidi ni èyí tí o ṣetán láti mú ọ̀rọ̀ ètò ìlera lo sí ìpele ọtun.

O ni apẹrẹ rẹ ní àwọn agbègbè tí o pèsè láti kọ àwọn ibi iṣé abẹ náà

Ó wà rọ àwọn ará ìlú láti lo ànfààní náà daradara .

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button