Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Amòye Ìdàgbàsókè Àwọn Ọmọdé Pé Fún Ìmojútó Òbí

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 446

Àwọn amòye nínú ìdàgbàsókè ọmọ tí rọ́ àwọn òbí láti ṣé àkitiyan ní tí pàápàá nínú títọ́ àwọn ọmọ wọ́n, wọ́n sì tún gbá àwùjọ níyànjú láti tọ́ àwọn ọmọ wọnyí dáradára.

Àwọn tí ọrọ náà kàn sọ èyí dì mímọ̀ níbí ìfilọ́lẹ̀ ìwé kàn tó pé àkọlé rẹ̀ ní “Lulu Learns” tó wáyé nílùú Ibadan, Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Oyo.

Níbi ìfilọ́lẹ̀ ìwé náà tí wọ́n pé ní, “Intentional Parenting”, níbí tí àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ mẹ́ta kàn tí ṣé ìjíròrò ọlọ́gbọ́n, tí fohùn ṣọ̀kan pé kí àwọn òbí ṣètò àkókò fún àwọn ọmọ wọ́n kí wọ́n sì wà ayé fún àwọn ọmọ nígbà gbogbo.

Olùpèsè àti òǹkọ̀wé ìwé náà, Arábìnrin Ronke Giwa-Onafuwa tí ó tún jẹ́ agbéròyìnjáde tẹnumọ́ pé àwọn òbí ní láti wá àkókò fún àwọn ọmọ wọ́n bí wọ́n ṣe ń wá àkókò fún àwọn ohun tí ó ṣe pàtàkì sí wọ́n. Ó ṣé àkíyèsí pé títọ́ ọmọ, òbí gbọ́dọ̀ ṣé àkitiyan lórí kíní á ń sọ́ fún wọ́n, òún wó là fí ń bá wọ́n sọ̀rọ̀, kíní á ń ṣé lójú wọ́n àti kíní á ń ṣé fún wọ́n, bíi lilù.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button