Adẹ́rìn-ín pòsónú ọmọ Nàìjíríà, Debo Adebayọ tí gbogbo ayé mọ̀ sí Macaroni ti gba ẹ̀bùn ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tuntun fún bí ó ti se fakọyọ jùlọ.
Àwọn gbajúgbajà òsèré bíi Kiekie, Toyin Abraham, Denrele Edun, Ọgbẹni Macaroni, Shegaz Bella, ni o péjú síbi ayẹyẹ naa.
Ní orí ẹ̀rọ ayélujára rẹ̀, Ọ̀gbẹ́ni Macaroni fí fán-án-rán fídíò léde, níbití ó tí fi ìdùnnú rẹ hàn, ti o si duoẹ lọwọ Ọlọrun, ẹbí, ọ̀rẹ́ àti àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ látàrí ìjáwé olúborí, èyí ti o si gba ẹ̀bùn ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tuntun.
Leave a Reply