Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara, AbdulRahman AbdulRasaz sọ wípé ìjọba òun yóò se akitiyan láti jẹ́ kí ìpínlẹ̀ Kwara jẹ́ àyè ìgbafẹ́ fún àwọn ènìyàn.
Nigba ti o n sọrọ ni ilu Lafiaji, ijọba ibilẹ Edu, nibi ayẹyẹ ọdun Sallah Nko. Gomina sọ wipe àṣà ti o dara wa ni ipinlẹ kwara, èyí ti o le è mú ìgbòòrò bá ètò ọrọ̀ ajé.
Ọdun Sallah Nko jẹ́ èyí tí o maa n waye ni ọdọọdun nibi ti gbogbo awọn ọmọ Lafiaji yoo ti péjú pésẹ̀ lati ki Emir pẹlu kikirun ọdun .
Leave a Reply