Ìwarìri ilẹ̀ pá ènìyàn kàn ní erékùṣù Indonesia tí Java, tó sì ṣé ìpalára fún o kéré jù ènìyàn mẹwàá, Ilé-iṣẹ́ idagiri àjálù tí Orílẹ̀-èdè náà BNPB sọ.
Agbẹnusọ Ilé-iṣẹ́ náà, Abdul Muhari sọ pé iwarìri náà bá àwọn ilé bí ọgọọgọrun jẹ́, àwọn ilé-iṣẹ́, ilé-ìwòsàn àtí àwọn ilé-ìwé ní àgbègbè Yogyakarta àtí Central Java.
Ìròyìn sọ pé kò sí ìkìlọ tsunami tó jáde.
Leave a Reply