Ìsẹ̀lẹ̀ Ìwarìri Ilẹ̀ Pá Èèyàn Kàn Ní Indonesia
Ìwarìri ilẹ̀ pá ènìyàn kàn ní erékùṣù Indonesia tí Java, tó sì ṣé ìpalára fún o kéré jù ènìyàn mẹwàá, Ilé-iṣẹ́ idagiri àjálù tí Orílẹ̀-èdè náà BNPB sọ.
Agbẹnusọ Ilé-iṣẹ́ náà, Abdul Muhari sọ pé iwarìri náà bá àwọn ilé bí ọgọọgọrun jẹ́,…