Take a fresh look at your lifestyle.

Àdelé Ọgá Àgbà Ọlọ́pàá Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bẹ̀rẹ̀ Ìṣẹ́

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 463

Àdelé Ọgá Àgbà Ọlọ́pàá Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ag. IGP Egbetokun Olukayode tí gbá iṣẹ́ ní Ilé-iṣẹ́ agbofinro ní Abuja, Olú-ìlú Nàìjíríà.

IGP Egbetokun ní Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu, GCFR, tí yán ní ọjọ́ kọkandinlogun 19th, Oṣù Kẹfà, ọdún 2023.

Ó gbá ipò lọwọ́ ọgá tẹlẹ rí IGP Usman Alkali Baba, ẹni tí o fẹyinti lẹyìn ọdún kárùndínlogójì 35 kó tó feyinti lẹ́nu iṣẹ́ Ọba.

Iṣipo pada náà ló wáyé láàárín àwọn méjèèjì ní Ọjọ́rú, ọjọ́ kọkanlelogun 21, oṣù kẹfà, ọdún 2023.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button