Gbajúgbajà olórin, David Adeleke, tí gbogbo ayé mọ̀ sí Davido ti fi àìdùnnú ọkàn hàn, tí ó sì sàpèjúwe àsìkò àyájọ́ “Bàbá” bí èyí tí ó le koko fún òun.
Akọrin náà sọ ọ̀rọ̀ náà di mímọ̀ lórí ẹ̀rọ ayélujára rẹ̀ ní ọjọ́ Àìkú, ọjọ́ kejìdínlógún, osù kẹfà ọdún 2023.
Davido, ẹni tí ó pàdànú ọmọkùnrin rẹ̀ àkọ́kọ́, tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́ta, Ifeanyi, ní osù kẹẹ̀wá ọdún 2022.
Leave a Reply