Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ jẹ́ ká máa ní ìgbàgbọ́ nínú ìjọba

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 276

Wọ́n ti rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti máa nígbàgbọ́ àti láti gbé ìjọba ní gbogbo ìpele nígbùnwọ́ láti jẹ́ kí àwọn tó wà nípò adarí le ṣiṣẹ́ wọn bótitọ́ àti bó ṣe yẹ.

Mínísítà fún ọkọ̀ òfurufú tẹ́lẹ̀ rí, Hadi Sirika ló gba ìmọ̀ràn yìí níbi ìbáraẹnisọ̀rọ̀ pẹ̀lú àwọn akọ̀ròyìn ilé ìjọba.

Ó sọ pé àwọn ará ìlú gbọ́dọ̀ fòpin sí ọ̀rọ̀ àìnígbàgbọ́, ní èyí tí ó ń fa àti máa furasí ìjọba.

Sirika tun fikun un pe kikun ijọba lọwọ yoo ṣe ipese ijọba to dara ati to munadoko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button