Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Ìgbìmọ̀ Kàn Gbóríyìn Fún Orílẹ̀-èdè Niger Fún Ààbò Ìbodé

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 159

Ìgbìmọ̀ tí Orílẹ̀-èdè yí fún Àṣà àtí ìṣé tí yìn Orílẹ̀-èdè Republic of Niger fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ológun tó lágbára pẹ̀lú Nàìjíríà látí jẹ́ kí ààbò tó péye wá ní ibodè látí dáàbòbo ìgbésí ayé àti àwọn òun-ìní ní àgbègbè ààlà tí àwọn orílẹ̀-èdè méjèèjì.

Olùdarí Gbogbogbò, Segun Runsewe ṣé ìyìn yìí ní ọfisi rẹ̀ nígbà tó gbá àwọn aṣojú tí àwọn ọgá àgbà ológun láti Superior Military College ní Niger Republic tó wà ní ọfisi rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí apakan tí àbẹ̀wò ikẹkọ wọ́n sì Nàìjíríà.

Nígbà tó gbá wọ́n ní àlejò Runsewe sọ pé yàtọ sí pé á jọ́ pààlà, àwọn orílẹ̀-èdè méjèèjì tún àwọn òún míràn tí á máa ń ṣé pọ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tí Àjọ Àgbáyé (UN), International Monetary Fund (IMF), Ìgbìmọ̀ Lake Chad Basin, Economic Community of West Africa State (ECOWAS), African Union (AU) Organization of Islamic Community (OIC) láàrín àwọn míràn.

Olórí àwọn aṣojú ṣé àfihàn ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ̀ pé àwọn mọ̀ rírí ìmọ àti òye tí wọ́n tí gbá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button