Aĺáṣẹ àpapọ̀, Voice of Nigeria (VON), Ọ̀gbẹ́ni Osita Okechukwu, ti rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti ní ìgbàgbọ́ nínú ààrẹ Bọla Tinubu, fún àtúnṣe ipò ìbáraeniṣepọ̀ ọrọ̀ Ajé Nàìjíríà.
Ọgbẹni Okechukwu, oludasilẹ ọmọ egbẹ All Progressives Congress (APC), pe ipe yii nigba tí o n fọrọ jomitoro ọrọ pẹlu awọn akọroyin ní ipinlẹ Enugu, ní ọjọ́ Aiku.
Aláṣẹ àpapọ̀ (DG) náà,sọ pé púpọ̀ nínú àwọn ọmọ Nàìjíríà mọ̀ńmọ̀n tàbí àìmọ̀ńmọ̀n kọyán ààrẹ Tinubu kéré.
Ọ̀gbẹ́ni Okechukwu sọ pé ó tẹ́ òun lọ́rùn pé ìṣèjọba ti sún sí iwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè nípasè pínpín tí gbogbo wọ́n gbámú ṣinṣin.
Leave a Reply