Balógun Ìkọ Cricket Australia Meg Lanning kó ní lè kópa nínú ìdíje “Women Ashes” bí wọ́n yóò ṣé kojú England, Cricket Australia kéde
Lanning, ẹní ọdún mọkanlelọgbọ̀n 31, ní àwọn onímọ̀ iṣegun òyìnbó tí rọ̀ kó dúró sílé fún itọju .
Wicketkeeper-batter Alyssa Healy ní yóò jẹ́ Balógun ẹgbẹ́ náà nígbàtí Tahlia McGrath yóò ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìgbákejì Balógun fún Ifẹsẹwọnsẹ náà.
Lanning, ẹni tí o tí gbá ife Àgbáyé Èrè Kirikẹ̀ẹ́tì tí àwọn Obínrin ní ẹmeji ọtọtọ, kó tó tún darapọ̀ mọ́ ìkọ náà ní Oṣù kíní ọdún yìí lẹ́yìn ìsinmi àìlera ọpọlọ Oṣu mẹfa. Béè náà ní o tún ṣé Balógun ìkọ Australia lọ́ sí ìdíje Twenty20 World Cup ẹlẹẹkarun irú rẹ̀ ní Oṣù tó tẹ̀le.
Leave a Reply