Ààrẹ Muhammadu Buhari yóò dúró ọ̀sẹ̀ kan síi ní London, United Kingdom,bí Dókítà eyín rẹ̀ ṣe sọ,tí ó sì ti ń ṣètọ́jú rẹ̀.
Dókítà ní láti ṣètọ́jú ààrẹ fún ọjọ́ márùn ún mìíràn tí ó sì ti bẹ̀rẹ̀ báyìí.
Ààrẹ Buhari darapọ̀ mọ́ àwọn adarí tókù lágbàáyé láti kópa nínú ìwúyè Ọba Charles kẹta,ní ọjọ́ kẹfà,oṣù Ebìbì, 2023.
Leave a Reply