Ìjọba àpapọ̀ ti fún àwọn tọ́rọ̀ kan nisè láti rí dájú wí pé wọn tèsíwájú nínú ètò náà, ni ìpínlẹ̀ Nasarawa àti Niger.
Olùdarí fún ètò náà, Ọ̀gbẹ́ni Suleiman Mukthar, lo sọ èyí di mímọ̀ fún àwọn oníròyìn ní lafia ni ìpínlẹ̀ Nasarawa.
Mukthar sàlàyé wí pé ètò yìí wà fún àtúnṣe nípa bí àwọn ọmọdé ṣe n kúrò ní ilé ẹ̀kọ́ àti àwọn ìwà ìbàjẹ́ ti wọ́n ń wù láwùjọ.
Ni ìrántí wí pé ọ̀físì ìgbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Yẹmi Osinbajo lo fi ìdí ètò yìí múlẹ nipasẹ olùdámọ̀ràn pàtàkì sí ààrẹ fún ọ̀rọ̀ ìlú tó wáyé , ni ọjọ́ kẹwàá oṣù Kejì ọdún 2022 ni olú ìlú Abuja.
Leave a Reply