Arákùnrin kan tí ọmọ rẹ ọmọ ọdún mẹ́rin fi ìbọn ṣeré ni ojú amóhùnmáwòrán.
Shane Osborne, yi jẹ ẹni ọdún máàrúnlélogójì ni wón fi ẹ̀sùn kàn nígbà tí àwọn alabagbe rẹ sọ nípa ọmọ ọdún mẹ́rin rẹ tó gbé dání ni òpópónà.
Arákùnrin náà ni, ohun o mọ ìgbà tí ọmọ náà bọ́ síta
Èyí bọ́sí oṣù kanaa tí ọmọ ọdún mẹ́fà kan náà yìn ìbọn pa olùkọ rẹ̀ ní ilè ẹ̀kọ́ Virginia Elementary, èyí tí àwọn olópàá pé ni ẹ̀ṣẹ̀ tí a mọ̀ọ́mọ̀ dá.
Ọláyinká Akíntọ́lá.
Leave a Reply