Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Ẹjọ́ Fagilé Ẹ̀sún Tí Afi Kan Ọgá Àgbà Àwọn Ọmọ Ológun 

0 233

Ilé Ẹjọ́ gíga jù ni Nàìjíríà tí fagilẹ́ èsùn nípa ọgá àgbà pátápátá fún àwọn ọmọ ológun ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Lt.General Farouk Yahaya àti Major General Stevenson Olabanji

Adájọ́ Justice Halima Abdulmalik lo pàṣẹ yìí lẹ̀yìn ìgbà tí o gbọ atótónu lati ẹnu bàrìsìta Pinya Garuba agbejọ́rọ̀ fún ọgá àgbà pátápátá fún àwọn ọmọ ológun, nigbati o rọ ilé ẹjọ́ láti wọ́ gilè èsùn náà

Ó ní ẹni tí yóò ṣe ẹlẹrìí níbi ìgbẹ̀jọ́ náà kó yọjú nítorí iṣẹ́ rẹ̀,o sí rọ ilé ẹjọ́ láti sún ìgbẹ̀jọ́ náà sì iwájú.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button