Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn ọmọ ogun orí òfurufú Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà ti dín agbára àwọn agbésùmọ̀mí kù ní ìpínlẹ̀ Niger

0 605

Ilé-iṣẹ́ ologun ofurufu lorilẹ-ede Naijiria, NAF ti yọ awọn olori ikọ Boko Haram meji ti wọn ti n wá ti pẹ́ pẹlu awọn ọmọ ẹgbẹ wọn tó tó ogoji ni ile itaja kan ti wọn kọ silẹ ni Kurebe, ni ijọba ibilẹ Shiroro ní ipinlẹ Niger.

 

Agbẹnusọ NAF, (Air Commodore) Wap Maigida, lo fi idi rẹ mulẹ ní pa aṣeyọri ikọlu orí afẹfẹ náà, O ṣe akiyesi pe awọn akojọpọ ologun orií ofurufu yoo tẹsiwaju lati fọwọ́sowọ́pọ̀ ki wọn ba le rẹ́yìn awọn iṣẹ ikọlu awọn  Boko Haram wọnyi

 

Gẹ́gẹ́ bíi oṣiṣẹ onímọ̀ ààbò kan, Ọ̀ná dí fún awọn onijagidijagan yii, Abu Ubaida ati Yusuf Abba nigbati awọn ikọlu inu afẹfẹ ti ọkọ ofurufu NAF ṣe pẹlu iṣẹ Whirl Punch, kọlu agbegbe wọn, ni kòpẹ́ kòpẹ́ yìí.

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button