Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà Ivory tẹ́lẹ̀ pè fún ìpin ọjọ́ orí fún ipò ààrẹ

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 264

Méjì nínú àwọn olórí òṣèlú orílẹ̀-èdè Ivory tí ń lọ sí ọgọ́rin ọdún,tí ìkan sì ti lé ní àádọ́rin ọdún, Jean-Louis Billon orílè-èdè Ivory Coast, tó jẹ́ Mínísítà ètò ìṣòwò tẹ́lẹ̀ kọ̀yìn sí.

Billion pè fún ìdápadà ìfòpinsí ọjọ́ orí ọdún márùndín-lọ́gọ́rin fún olùdupò ààrẹ lásìkò tó ń sọ̀rọ̀ lórí ètò  asọ̀rọ̀mágbèsì kan.

Ó ń dojúkọ àwọn gbajúgbajà òṣèlú Ivory , Alassane Ouattara, Laurent Gbagbo àti ààrẹ ẹgbẹ́ òṣèlú tiẹ̀ náà, Henri Konan Bédié,níná o kósì ìkankan nínú wọn tó ti sọ síta kí gbogbo ayé gbọ́.

Mínísítà ètò ìṣòwò tẹ́lẹ̀ ń tún ṣàgbéyẹ̀wò ìpinnu tí ilé-iṣẹ́ òṣèlú PDCI  tó tún ń yan Bédié,ààrẹ tẹ́lẹ̀,tó tún jẹ́ ọmọ ọdún méjìdín-láàdọ́rùn ùn gẹ́gẹ́ bí olùdíje kan ṣoṣo láti sojú ẹgbẹ́.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button