Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Káwọ́rọ̀ Lórí Ìsàtúpalẹ̀ Òfin Tí Ó Dínàmọ́ Ìgbéyàwó Akọ-sákọ Àti Abo-sábo

0 231

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin kékeré ti ìlú Abuja ti ká ọwọ́ rọ̀ lórí ṣíṣe àtúpalẹ̀ òfin tí ó de ìgbéyàwó Akọ-sí-akọ àti Abo-sí-abo. (same sex marriage prohibiton Act, 2013.

 

Ọnẹrébù Muda Lawal ni ó se agbátẹrù òfin náà, eléyìí tí ó yẹ kí ó rí ìtẹ́wọ́gbà ẹlẹ́ẹ̀kejì ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin, sùgbọ́n ó rí ìdádúró látàrí àwọn ìmọ̀ràn tí ó wáyé lori rẹ.

 

Ẹni tí ó fi òfin náà léde sọ wípé ìgbéyàwó akọ-sákọ àti abo-sábo lòdì sí àṣà àti ìṣe wa ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ó sì pè fún kíkorò ojú sí irú àṣà burúkú bẹ́ẹ̀.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button