Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Àpapọ̀ Ti Ṣe Àfilọ́lẹ̀ Ilé- Iṣẹ́ Fún Ìpèsè Oúnjẹ lọ́pọ̀ Yanturu

0 328

Ìjọba àpapọ̀ pẹ̀lu ìfọwọ́sowọ́pọ̀ báńkì àpapọ̀ ilẹ̀ adúláwọ̀, African Development Bank (AFDB), báńkì ìdàgbàsókè mùsùlùmí, Islamic Development Bank (IDB), àti àjọ àgbáyé fún ìnáwó ètò ọ̀gbìn

(IFAD) ti se àfilọ́lẹ̀ ilé isẹ́ tí ó wà fún ìdàgbàsókè ètò ọ̀gbìn fún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní ìlú Àbújá.

 

Wọ́n fi ètò náà lọ́lẹ̀ láti se ìgúpá àti àtúntò ẹka ètò ọ̀gbìn fún ìpèsè iṣẹ́, oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu àti àlékún ọrọ̀ ajé orílẹ̀ èdè wa.

 

Adarí báńkì ilẹ̀ adúláwọ̀, ọ̀mọ̀wé Akinwumi Adesina rọ gbogbo ẹka ìjọba fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ wọn láti mú kí ètò náà kó ẹsẹ járí.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button