Take a fresh look at your lifestyle.

Àyípadà Ojú Ọjọ́ Ni Ó Fa Omíyalé

0 345

Ààrẹ Miuhammadu Buhari ti sọ pé orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ń kojú ìpèníjà àyípadà ojú ọjọ́, òhun ni ó fa omíyalé ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àgbègbè, tí ọ̀dá òjò sì ń sẹlẹ̀ ní apá àréwá orílẹ̀ èdè wa.

 

Ààrẹ wòye ọ̀rọ̀ yìi ́ní Seoul, South Korea nígbà tí ó ń bá akọ̀wé àgbà àjọ àgbáyé tẹ́lẹ̀ rí, Ban Ki- moon tàkùrọ̀sọ níbi àjọ àgbáyé ti ọdún 2022.

 

Ààrẹ  Buhari àti àwọn ènìyàn rẹ̀ sọ ipa tí kíkópa okùnrin àti obìnrin nínú ètò ìjọba jẹ́, wọ́n sì pè fún fífi òpin sí ogun tí ó ń lọ lọ́wọ́ ní orílẹ̀ èdè Ukraine

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button