Super Falcons ń ṣé aṣe kagba igbaradi fún ifẹsẹwọnsẹ ọlọrẹ sọrẹ wọ́n pẹ̀lú Japan ní Kobe.
Lẹyìn tí ìkọ Améríkà tí gbó ewúro sí wọn lójú lẹ́ẹ̀méjì ọtọtọ, Nàìjíríà yóò gbìyànju láti borí ìkọ Japan tí wọn gbá ìfé ìdíje Àgbáyé ní ọdún 2011.
Àkọnímọ́ọ̀gbá Super Falcons Randy Waldrum sọ pé, ifẹsẹwọnsẹ náà yóò jẹ ànfààní tó dára láti ṣé idanwo fún àwọn agbàbọ́ọ̀lù òun.
Nibayìí, àwọn agbàbọ́ọ̀lù mẹẹdogun loti wa ni ibudó, àwọn níwọnyí
*Chiamaka Nnadozie
*Nkiruka Obidinma
*Ogo Ogbonna
*Akudo Ogbonna
*Jumoke Alani
*Deborah Abiodun
*Esther Onyenezide
* Ashleigh Plumptre
*Rasheedat Ajibade
*Alafia Efih
*Osinachi Ohale
* Michelle Alozie
* Ifeoma Onumonu
*Florish Sabastine
*Christy Ucheibe
Lekan Orenuga
Leave a Reply