Ààre Muhammadu Buhari ti ju ọwọ́ káre sí gómìnà ìpínlẹ̀ Ímò níbi ìlàkàkà rẹ̀ láti pèsè àwọn ohun amáyéderùn.
Ààrẹ Buhari sọ pé gómìnà náà ti kọ ìtàn rere sílẹ̀ nípa isẹ́ ribiribi tí ó ń se.
Ààre gbé òsùbà fún-un ní ọjọ́ ìségun, ní ìlú òwèrì tíí se olú ìlú ìpínlẹ̀ ímò, nígbà tí ó se àbẹ̀wò síbẹ̀.
Ààrẹ Bùhárí ti Gbé Oríyìn Fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Ímò
Leave a Reply