Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Mínísítà fọwọ́sí ètò Àbojútó Àti àgbéyẹ̀wò ní orílẹ̀-èdè

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 251

Ìgbìmọ̀ Aláse àpapọ̀ ti fọwọ́sí ètò ìmúlò tuntun fún ìgbékalẹ̀ iṣé  àbojútó àti àgbéyẹ̀wò ní Nìàjíríà.

Eto naa ni  amọ si Eto Abojuto ati agbeyẹwo Orilẹ-ede.

Minisita fun eto iṣuna, inawo ati eto  orilẹ-ede, Zainab Ahmed fi eyi han lasiko ti o n ṣe alaye fun awọn oniroyin Ile-iṣẹ aarẹ ni ipari ipade minisita ti ọsẹ yii, ti aarẹ Muhammadu Buhari dari.

Ahmed sọ pe, eto imulo naa yoo ṣe iranlọwọ lati mu ilọsiwaju to dara ba igbe aye awọn ara ilu ati  idagbasoke-ọrọ-aje  orilẹ-ede.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button