Ìyanṣẹ́lódì ASUU: Ìgbìmọ̀ Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga fáfítì Nàìjíríà NUC, dúró lórí Àṣẹ rẹ̀ Fún Àwọn Alákòóso
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Ìgbìmọ̀ Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga Orílẹ̀-èdè NUC, sọ pé ó ti ṣetán láti ṣe atọ̀nà ìjíròrò àti àjọṣepọ̀ tó dánmọ́rán pẹ̀lú àwọn tí ó níí ṣe pàtàkì,gẹ́gẹ́ bí ó ṣe fẹ́ jẹ́ alábojútó ètò ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí kò kojú ìdààmú kankan.
Akọwe Alaṣẹ Igbimọ, Ọjọgbọn Adamu Rasheed sọ eyi ni ilu Abuja lakoko ifilọlẹ iṣakoso ifasẹyin ọdun 2022 pẹlu Awọn Alakoso Awọn ile-ẹkọ giga fafiti Naijiria, ti Igbimọ naa ṣagbatẹ ru rẹ.
Ojogbon Rasheed sọ pe ifikunlukun naa gbọdọ da lori afihan ati atilẹyin awọn akitiyan Minisita fun eto Ẹkọ, Adamu Adamu, Ile-iṣẹ Ẹkọ ti Ijọba apapọ ati awọn ti oro kan,ti n lọ lọwọ lati ṣe idaniloju iduroṣinṣin ati lati ri pe opin de ba idaṣẹsilẹ ti nlọ lọwọ ni awọn ile-ẹkọ giga ti gbogbo eniyan orilẹ-ede.
Leave a Reply