Ààrẹ Muhammadu Buhari ti rọ ilé ẹjọ́ pé kí wọ́n má ṣe já àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kulẹ̀ kí wọ́n baà lè fọkàn tán wọn.
O ṣe ipe naa ni ọjọ Aje, nibi ibura adajọ Olukayode Ariwoola gẹgẹ bi adele adajọ agba lorilẹ ede Naijiria (CJN), lẹyin ti Adajọ Ibrahim Tanko Muhammad ti fi ipo silẹ nitori ilera.
Aare naa sọ pe bi orilẹ-ede ti n mura silẹ fun idibo gbogbogbo 2023, awọn onidajọ ti ile-ẹjọ giga julọ ko gbọdọ figba-kan-bọkan-ninu.
Leave a Reply