Take a fresh look at your lifestyle.

Mo sinmi iṣẹ́ báyìí ná – Ibrahim Muhammad

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 291

Adájọ́ àgbà lórílẹ̀-èdè Nàì̀jíríà,Onídájọ́ Ibrahim Tanko Muhammad, ti kọ̀wé fi ipò sílẹ̀.

Oluranlọwọ lórí ètò ibaraẹnisọrọ sí CJN, Ọgbẹni Ahuraka Isah fi ìdí rẹẹ̀ mulẹ fún àwọn akọroyin lórí ìdájọ́ ní Abuja ní ọjọ́ Ajé.

Oníròyìn Voice of Nigeria sọ pé gẹ́gẹ́ bíi ìwádìí, eto n lọ lọwọ fun Aarẹ Muhammadu Buhari lati bura fun adajọ agba julọ ti ile-ẹjọ giga julọ ti o n jẹ, Onidajọ Olukayọde Ariwoola,lati kọkọ di ipo naa mu gẹgẹ bi adajọ  agba lorilẹ-ede Naijiria.

Alaye kikun nigbamii… ..

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button