Take a fresh look at your lifestyle.

Ìkọlù Pápá ọkọ̀ òfurufú Kàdúná:ikọ̀ Àwọn aṣojú bẹ̀rẹ̀ ìwádìí

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 252

Aṣojú ikọ̀ Minọ́rítì  ní Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ti pè fún ìwádìí kíkún ní kíákíá sí nǹkan tí ó fa  ìkọlù àti bí àwọn oníjàgídíjàgan ṣe já Pápá ọkọ̀ òfurufú  Kàdúnà gbà ní ọjọ́ àbámẹ́ta.

Ikọ naa tun ṣalaye iyalẹnu rẹ lori ohun ti o ṣapejuwe bi igbabọde aabo ti o han gbangba ni papa ọkọ ofurufu ti o fa ikọlu ọhun.

Ninu atẹjade kan ti Aṣáájú Kekere Ile naa, Ndudi Elumelu fowo si, igbimọ naa rọ ijọba lati yara ṣe eto aabo ni gbogbo awọn papa ọkọ ofurufu  orilẹ-ede ati awọn ohun elo apejọpọ gbogbo eniyan lati dina iru ikọlu naa nigbamiran.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button