Ilé ìfowópamọ́ Àgbáyé Pè Fún Àwọn Àtunṣe Ìgbékalè Láti yọ Àwọn ọmọ Nàìjíríà kúrò Nínú Òsì
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Ẹgbẹ́ ilé ìfowópamọ́ Àgbáyé sọ pé ìgbékalẹ̀ àtúnṣe tí ó jinlẹ̀ ṣe pàtàkì ní kíákíá láti yọ àwọn mílíọ̀nù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kúrò nínú ìpọ́njú,ó kìlọ̀ pé ìdá mẹ́tàdín-lógún àwọn òṣìṣẹ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni ó ní iṣẹ́ tó le gbani lọ́wọ́ òṣì.
Eyi jẹ afihan ninu ijabọ ile-ifowopamọ Agbaye kan ti akọle rẹ jẹ, “Ọjọ iwaju to dara fun Gbogbo Awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria: Igbelewọn Osi Naijiria 2022”.
Ile-ifowopamọ ọhun kilọ pe Naijiria lọwọlọwọ n dojukọ idagbasoke ti o lọra,aini oluṣiṣẹ to to,iṣẹ ọja ti ko lagbara, idojukọ igboya, eyiti o ti ko jẹ ki ipọnju Naijiria dinku.
Leave a Reply