Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà yóò ṣagbátẹrù àpérò Ìyípadà PHC Ní ìlú Àbújá

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 336

Ìjọba Nàìjíríà nípasẹ̀ ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó ìdàgbàsókè ètò ìlera alákọ́bẹ̀rẹ̀ (NPHCDA), ti ṣètò láti ṣagbátẹrù àpérò Ìtọ́jú Ìlera ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀.

Pataki Apero naa ni lati ṣe ifilọlẹ eto tuntun lati yi itọju ilera akọkọ pada ni orilẹ-ede.

Minisita fun eto ilera lorilẹ-ede Naijiria, Dokita Osagie Ehanire, ti o gbimọ  apero naa Ni ilu Abuja, sọ pe apejọ Itọju Ilera alakọbẹrẹ yii yoo waye ni ọjọ kẹrinle-logun ati ọjọ kẹẹdọgbọn, Oṣu Kẹta, ọdun 2022, ni Abuja.

Minisita naa sọ pe ida mẹtale-logoji ninu ida ọgọrun awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria lo laanfani si eto ilera alakọbẹrẹ to dangajia pẹlu dokita mẹrin pere  fun ọgọrun mẹwa eniyan, ida kan  oṣuwọn ti o kere ju ti ajọ ibaraẹniṣepọ agbaye (UN), fun ilera ipilẹ

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button