Take a fresh look at your lifestyle.

FCTA ń bèrè ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn oníròyìn Fún Ètò lílọ bíbọ̀ Tí ó múnádóko Ní ìlú Àbújá

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 231

Ìjọba olú-ìlú fún lílọ bíbọ̀ ní Nàìjíríà, FCTA, ti ṣe àfihàn àwọn oníròyìn gẹ́gẹ́ bí alábáṣepọ̀ pàtàkì tó le mú kí ìdàgbàsókè àti ìṣàkóso tó múnádóko ní ẹ̀ka gbígbélọ bọ̀ ní ìlú Àbújá, olú-ìlú orílẹ̀-èdè rọrùn

Akọwe ile-iṣe FCT ẹka gbigbelọ ati bibọ, Hon. Zakari Angulu Dobi, lo sọ eyi di mimọ lasiko ifọrọwerọ pẹlu awọn oniroyin ti wọn ṣe abẹwo si, lasiko ayẹyẹ ọjọ ibi rẹ.

Akọwe naa wa pe akiyesi si ipa pataki ti awọn oniroyin n ko ni awujọ,o sọ pe eka gbigbelọ bọ yoo fọwọsowọpọ nigbagbogbo pẹlu awọn oṣiṣẹ oniroyin paapaa julọ awọn ọmọ ẹgbẹ oniroyin minisita olu ilu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button