Take a fresh look at your lifestyle.

Idunnu subu layo AY Makun.

Eyitayo Fauziat Oyetunji

0 260

Olorun ti fi omo tuntun jinki Gbajugbaja apanilẹrin Naijiria, AY Makun ati iyawo rẹ Mabel.

Apanilẹrin naa polongo iroyin ayọ naa lori oju opo wẹẹbu Insitagiramu rẹ pẹlu fidio iyawo rẹ ati ọmọ tuntun wọn.

Eyi ni omo eleekeji ti tọkọtaya naa yoo bi  lẹhin ọmọ akọkọ wọn ti won bi ni ọdun mẹtala sẹhin.

Ay sọ ninu ifiweranṣẹ naa pe igbẹkẹle wọn ninu Ọlọrun lati bi ọmọ miiran tọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button