Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Mákindé fi ìdí ikú gómìnà nígbà kan rí, Akálà múlẹ̀

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 282

Gómìnà Ṣèyí Mákindé ti Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti fi ìdí ikú gómìnà tẹ́lẹ̀ nígbà kan rí, Adébáyò Àlàó-Akálà múlẹ̀.

Makinde jabọ ọrọ iku naa nigba ti wọn pe e lati sọrọ inu rere  nibi adura ijọsin ti n lọ lọwọ fun awọn oṣiṣẹ ipinlẹ Ọyọ.

Gómìnà náà, tó sọ pé òun rí ìròyìn náà gbà níbi ayẹyẹ náà dípò kó máa kéde ọ̀rọ̀ kan, ó pè fún ìdákẹ́jẹ́ẹ́ fún ìṣẹ́jú kan, ó sì ní kí wọ́n parí ètò tó ń lọ lọ́wọ́ lọgan.

Olori ẹgbẹ APC tẹlẹ ri faye silẹ  lowurọ ọjọ Iṣẹgun to kọja yii loju orun nile rẹ ilu Ogbomọṣọ.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button