Take a fresh look at your lifestyle.

Aare Buhari Yan Doyin Salami Gẹgẹ Bi Oludamoran Agba Fun Eto Ọrọ Aje

0 334

Oludamọran agba fun eto ọrọ aje ti Aarẹ Buhari sẹsẹ yan ni Ọjọgbọn Doyin Salami.

Oludamoran fun Aare lori eto iroyin ati igbokegbodo, Femi Adesina lo se afihan eyi ninu atẹjade kan to fi sita lọjọ Isẹgun.

 

Ọjọgbọn Doyin Salami, ẹni ti o jẹ ọmọ ọdun mọkandinlọgọta, ni yoo maa mojuto gbogbo awọn ọran lori eto-ọrọ aje lorilẹ ede Naijiria, yoo si tu ma gba Aarẹ ni imọran lori awọn ọna ti eto ọrọ aje naa yoo fi tuba, ti yoo si fi tusẹ.

 

Tolulope Akinseye

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button