Take a fresh look at your lifestyle.

Asaba Setán Láti Gbàlejó Ayẹyẹ Eré Ìdárayá Fọ́dún 2022

0 245

Ìgbìmọ̀ tó ń bójútó ètò eré ìdárayá ti fọwọ́sí oṣù kọkànlá, ọjọ́ kejì  sí ọjọ́ karunlelogun, ọdún 2022 gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ fún ayẹyẹ eré ìdárayá kokanlelogun ní ìpínlẹ̀ Delta. Ayẹye náà ni àkọ́lé rè jé Asaba 2022 .

Minisita fun idagbasoke awọn ọdọ ati awọn ere idaraya, Sunday Dare ti ṣe apejuwe ipinle Delta gẹgẹ bi ipinlẹ ti o  gbegba oroke nibi pipese talenti fun idagbasoke ere idaraya ni orilẹ-ede Naijiria

Nigba ti o n sọrọ ni ilu Asaba, olu ilu Delta, Minisita naa dupe lọwọ ipinlẹ naa fun gbigbalejo gbogbo ipade ere idaraya, o si so wi pe aseyori orile-ede Naijiria ninu ere idaraya ko pe laisi iranlọwọ ipinlẹ naa, ati awọn ilọsiwaju nla awọn elere idaraya ti orilẹ ede Naijiria.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button