Take a fresh look at your lifestyle.

Ààjọ NIMC Ṣe Àkọsílẹ̀ Ìforúkọsílẹ Fún Àádọ́rin Mílíónù Ọmọ Nàíjírìa

0 254

Ìgbìmọ̀ tó ń mójútó  ìṣàkóso  káàdì ìdánimọ̀ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà NIMC ti ṣàlàyé pé ó ti rí ìlọsíwájú rere pẹ̀lú bí ó ṣe ṣe àkọsílẹ̀  ìforúkọsílẹ̀ fún àwọn tí ó lé ní àádọ́rin milionu àwọn ọmọ Nàìjíríà.

Gẹgẹ bi atẹjade kan ti adari igbimọ naa (NIMC) fowo si, Ọgbẹni Kayode Adegoke sọ pe Oludari agba NIMC, Aliyu Aziz, sọ pe igbimọ naa ni anfani lati ṣe aṣeyọri iṣẹ naa nitori awọn ipa pataki ti  aarẹ Muhammadu Buhari ko. Bakan naa o kan saara si Minisita fun Ibaraẹnisọrọ, ọjọgbọn Isa Pantami, awọn osisẹ to gbounjẹ fẹgbẹ gbawo bẹ, ajọ FEPS ati awọn alabaṣepọ pataki miiran ni eka idanimọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button