Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari Yóò Yẹ́ Àpẹ́rò EXPO 2020 Dubai Sí

0 256

Ààrẹ Muhammadu Buhari yóò kúrò ní ìlú Abuja lóòní ọjọ́ Ọjọ́bọ̀ láti lọ sí EXPO 2020 Dubai ni orílẹ̀ èdè United Arab Emirates (UAE).  

EXPO 2020 Dubai, ti akori rẹ jẹ, “Isọkan ọkan, Ṣiṣẹda ojo iwaju” eyi yoo jẹ anfaani fun Nigeria lati darapọ mọ awọn orilẹ-ede miiran pẹlu ajọṣepọ to ni itumọ ti o si pese ọjọ iwaju ti o dara julọ fun gbogbo eniyan.”

Apewo naa yoo pese aye fun awọn aṣoju Naijiria lati ṣe afihan awọn ilọsiwaju pataki ninu eto-ọrọ aje lati bi  ọdun mẹfa sẹhin gẹgẹ bi ipilẹ fun ṣiṣe orilẹ-ede naa ni ibi ko-se-e-ma-lọ fun awọn  oludokowo okeere.

 

Tolulope Akinseye

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button