Àwọn ikọ̀ omo ogun Nàìjíríà HADIN KAI (OPHK) ti fàbùkù kan àwọn ikọ̀ ISWAP tó lé ní aadota nínú ìkọlù tó sẹlẹ̀ láàrín àwọn méjèèjì ní agbègbè Askira, Ìlu Borno.
Iya ti wọn fi jẹ awọn ikọ ISWAP ko kere rara; nigba ti wọn mu olori wọn balẹ, ti wọn si tun sọ awon ọkọ̀ ogun wọn deeru.
Tolulọpẹ Akinsẹyẹ
Leave a Reply