Àárẹ Buhari gbéra sàsà láti orílẹ̀ èdè South Africa, ó fìlu Durban sílẹ̀; Abuja ló guń lẹ̀ sí, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Pápá ọkọ̀ òfúrufú ti Shaka ló ti gbéra, ní déédé aago mókànlá.
Ààrẹ naa, ti o ti wa ni Durban, South Africa lati ọjọ Abamẹta, darapọ mọ awọn oludari agbaye miiran lati kopa ninu ipade apero ti ilẹ Afrika to waye lojo Aje
Ninu ipade naa, Aarẹ bẹbẹ fun ifowosowopọ to kun ojuwọn laarin awọn orilẹ- ede Afirika, lati mu iṣowo burẹkẹ si ni ilẹ Afrika
Tolulọpẹ Akinsẹyẹ
Leave a Reply