Ìjàǹbá Iná Àbújá: Mínísítà fún ọmọnìyàn kẹ́dùn pẹ̀lú àwọn olùfaragbá
Mínísítà fún ètò ọmọnìyàn, ètò àjálù àti ìdàgbàsókè àwùjọ, Sadiya Umar Farouq ti kẹ́dùn lórí ìpàdánù ọjà àti dúkìá tí ó tó bílíọ̀nù owó dọ́là Náírà, nínú ìṣẹ̀lẹ̀ iná tó wáyé ní ilé…