Ìgbákejì Ààrẹ Zimbabwe Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Mínísítà Ilẹ̀ Òkèèrè Tí Vatican
Ìgbákejì Ààrẹ Zimbabwe, Constantino Chiwenga, ṣé ìpàdé pẹ̀lú Mínísítà ile òkèèrè tí Vatican, Archbishop Paul Richard Gallagher, ní Rome ní Ọjọ́ Àbámẹ́ta.
Ìpàdé náà dá lórí àwọn ìpèníjà ìṣèlú àti ètò ọrọ-àjé tí Zimbabwe, pẹ̀lú àwọn…