Wike ṣèdárò pẹ̀lú Ortom lórí ikú àbúrò rẹ̀
Mínísítà Nàìjíríà fún Olú Ìlú (FCT), Ọ̀gbẹ́ni Nyesom Wike, ti ṣèdárò pẹ̀lú Gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue nígbà kan rí, Samuel Ortom, lórí ikú ọmọkùnrin àbúrò rẹ̀, Ọgbẹni Bernard Tyozenda Ortom.
Ninu alaye kan lati…